Omulu
Ajibero !!!
A to to !!!
Ago n’ile, n’ile
n’ile ma dagó
Omolu, Obaluaye
Madago
Ago n’ile ago
Ò
ní a ló
ìjeníìyà
Ajàgun
tó ló
Ìjeníìyà
olúwàié
Táálá
bé okùnrin
O
táálá bé okùnrin
Wa
ki ló kun
Táálá
bé okùnrin .
Abénilorí
ìbé
Rí
ó ní je
olúwàié
Táálá
bé okùnrin
Nagô lê lê
Nagô lú lá
Ke wa saorô
Nagô lê lê
Lori jena ban ban
Osi ê ko mo e iwo
Lori jena ban ban
O si é ko obô lê ô
Omolú Kíí bèrú jà
Kòlòbó se a je nbo
Kòlòbó se a je nbo
Kòlòbó se a je nbo
Aráayé.
Olórí ìjeníiyà a pàdé
Olorí
pa
Olórí ìjeníiyà a pàdé
Olorí
pa
Omulu bêfa raêê
Omulu bêfa rao
Omulu bêfa raêê
Omulu bêfa raoooo
Egui lê bi bo kan
Egui lê bi bo kan
Aê aê egui lê bi bo kan
Àká
ki fàbò wíwà
Àká
ki fàbò wíwà
Omolú pè olóre a àwúre e
Kú
àbó
Omolú pè
olóre a àwúre
e
Kú àbó
Sé
ó gbèje
Kóró
nló
Awo kóró
nló
Sé ó gbèje
Kóró
nló