Kawô kabiesilê Oba !!! Kawô Kabiesile!!Oba nise Kawo!!! Kabiesile!
Àwa dúpé ó oba dodé
A dúpé ó oba dodé.
A dupé ni mòn oba e kú alé
A dupé ni mòn oba e kú alé
Ó wá , wá nilè
A dupé ni mòn oba e kú alé
Fura ti ´ná, Fura ti ´ná e ,
Fura ti ´ná,
Àrá lò si sá jó
Fura ti ´ná, Fura ti ´ná e ,
Fura ti ´ná,
Àrá lò si sá Jô
Ìbà òrìsà
Ìbà Onílè
Onílè mo júbà o
Ìbà òrìsà , Ìbà Onílè
Onílè mo júbà o
Oba nisa elo ke odo
Oberioman
Oba nisa elo ke odo
Oba koso aiô
Olokum marae
Aira aira Oba kosó
Marae
Aira aira aira aira Oba kosó
Aira ke ké soro
Luani mai man se lê
Orisa ke fa rewa
Aira aira ô
Aira òjo
Mó péré sè.
A mó péré sè
Aira ô lê lê
Aira ô lê lê
Firiman firiman
Firiman abaizo
Aira aira firiman abaizo
Sangô kó ekó
Labawira la izo
Baba o dupé
Baba o dupé
Sangô mi kaô
Baba o dupé
Sàngó dê mariwo
Sàngó dê mariwo
Aira aira ô
Sàngó e pa bi àrá
aáyé aáyé
Sàngó e pa bi àrá
aáyé aáyé